Oju ewe ile


:Itumo ede

English
Español
Ελληνικά / Elliniká
Română
Èdè Yorùbá

                                        

:Awon oju ewe miiran

Ida

aworan oju opo lorii itakun agbaye

Awon oro to ta koko

Olubasoro

Akosile ipese

Awon itokasi to wulo

Imo eto eko bibaraenise laarin egbe ati lawujo


Lourdes Sada

Nipa Phil Bartle, PhD


Itumo ede je sise nipa Odekunle Olusegun


Irisi Olulo

Ogbontarigi ninu Sise itumo ede lorii itakun agbaye ni ede Spanish, Sise agbekale afokanfojuya aworan, Sise alamojuto oju opo lorii itakun agbaye, Oludarii itumo ede (Spanish, Portuguese, Catalan, Basque, Galego, Greek, Romanian, Turkish).

Lourdes je omo bibi Huesca ni Orile-ede Spain. O bere iwe kika ninu imo oloyinbo to jemo oogun, ohun to mbe ninu afefe(kemisiri) ati imo ero ayelujara. Ni opolopo odun seyin, o lo si ilu Brussels nibiti o ti ko ede French ni ibudo ede kiko ni Ile-eko giga ti Louvain. Ni ojo kan, o rii lori ero ayelujara pe won nwa awon ti won le se itumo ede, o si darapo mo won lati tumo gbogbo oju opo itakun agbaye naa si ede Spanish. Lati igba naa, to le ni odun mewa seyin, ko tii siwo fifiaraenijinfunse.


Lourdes Sada, 2010

O bi omo meji ti won ko je ki owo-o re ko dile.Botiwukori, lojoojumo, yoo wa aaye ati okun lati se itumo ede awon oju ewe lorii itakun agbaye fun awon Ile-ise ti ko si fun ere jije. Fun oju opo itakun agbaye wa nikan, o ti se itumo ede akosile to le ni igba, leyi to ku die ko je gbogbo oju opo itakun agbaye na, osi tun se adari fun awon olutumo ede to seku.


Lourdes Sada, Serres Royales, 2008

O tun nse Oludari fun awon afiraenijinfunse ti nse itumo awon ede miiran, o si tun npese imoran to yanranti ati iwuri fun awon olutumo ede to seku. O ti ko araa re ni awon kan ninu eto yiye aworan sise wo finnifinni, o si tun se apo-iwe fun awon aworan sise lorii oju opo itakun agbaye. Fun gbogbo ipa to ti ko lorii oju opo lorii itakun agbaye yii, o ti waa di ojogbon ninu imo oju opo lorii itakun agbaye. O ti se agbekale afokanfojuya aworan ati yiyipada awon oju ewe ti o wa lorii oju opo lorii itakun agbaye si ilana tuntun ti o mo, ti ko diju, ti o je ko tunbo rorun fun eeyan lati ka, ti o je ki o rorun sii lati seto itumo ede fun gbigbe sorii oju opo lorii itakun agbaye.

Die lara awon ohun ti o je-e logun nipa ede Spanish ni a le ri ni Errores."

Ibasepo to gun rege re pelu oju opo lorii itakun agbaye, jijiroro lorii oopolopo ninu afokansun ni igba miran ti o jemo fifo si wewe ni oju ona laarin ede oyinbo ati Spanish ti yorisi ki o ni ekunrere oye nipa ilana riro agbegbe lagbara. Nitorinaa, o tun ti mojuto opolopo ibeere lati odo opolopo awon to nka ede Spanish ni oju opo lorii itakun agbaye naa.

Lourdes gba ebun ami igboriyin lati agbajo isokan awon orile-ede, eka ti afiraenijinfunse lorii itakun agbaye ni odun 2006.

Ope ni fun Lourdes Sada fun iranlowo re nipa mimu ki oju opo itakun agbaye yii ko tunbo wulo, ki o si je alarinrin.

––»«––

Ti o ba se eda lati oju opo lorii itakun agbaye yii,
jowo gbe osuba fun (awon)Olukowe yii ki o si se itokasi re si cec.vcn.bc.ca/cmp/

 Tito ona to ni ikojuujasi to kere julo maa nso gbogbo odo ati awon kan lara okunrin di wiwo


© Ase Onise 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Afokanfojuya aworan nipa Lourdes Sada
––»«––
Imukosuwon to kehin: 2015.01.31

 Oju ewe ile