oju iwe kini
Awon Ede Miran

Bahasa Indonesia
English
Español
Français
Ελληνικά / Elliniká
Italiano
Èdè Yorùbá

                                        

Awon Oju Iwe Miran

Modulu

Aworan Ojula Ayelujara

Koko

Olubasoro

Iwe Iwulo

Ona Asopo ti O wulo

Sociology


Igbejade Agbara Ojuami

nipa Phil Bartle, PhD

itumo nipase OLUTUNMBI, TobiLati se amulo aye fini fini lori oju iwe ero ayelujara, a ni lati yo awon igbejade agbara oju ami ti a n lo lati se idanileko. Awon iwe ase won yi ni osi wa fun lilo awon awon ti o n se koriya fun awujo ati awon oludari ati awon olu dani leko. ko ki n se gbogbo iwe ikeko ni o ti ni igbejade agbara ojuami. Ise si n lo lori eyi lati wa awon olu faraji ti yi o ran wa lowo. Nje o nife lati darapo mo egbe yi? Ti ami kan kan ba wa ni ako ri iwe yi ti o juwe "Agbara", jowo ko we si wa, awa yio si fi apeere igbejade agbara oju ami sowo si o nipa asomo. Jowo je ki a mo bi o ti se n lo oun elo yi ati nipa re ati ise re.

Opolopo Igbejade Agbara Ojuami ni o wa: (1) modulu kini, sise imura, ti a dipo ninu faili (ti os wa ni edee Somali);(2) modulu keji, sise imura, ninu faili (3) modulu keta, nini iseto, ninu faili;(4) modulu kerin, ninu igbese, ninu faili bakana;(5) modulu karun, mimu awon igbese duro, katun awon igbese yi gbe; ati awon ifihan ototo: Ewi lati owo Lao Tsu, Lo si odo awon Eniyan (ni orisirisi edee), ati awon ayika koriya, pelu aworan apejuwe ti ile Afirika. aon olufarajin n sise lori eyaa ti Portuguese ati Spani.

Awon Eyaa ti html (oju we ayelujara) ati ascii (oro faili) si wa ninu aaye yi, ni ofe fun lilo. jowo so fun wa nkan ti o n se at bi oti se n lo ohun elo yi.

––»«––

Ti o ba je eni ti o fiyesi awon ilana agbara (iro ni lagbara) fun awon agbegbe olowo kekere, jowo ko we si ; omowe, olugbeja, olu danileko, awon osise, awon ti o n se koriya, alakoso, asseto, oluwadi, omo ile-iwe, oluko. Awa nife si lati gbo lati odo re. Awa nife si iforo jomitoro oro, ijiroro ati ibanisoro. Wo awon egbe ijiroro ni ori ijapo ti o wulo.


Ti o ba se edaa iwe lati ori aaye yi, jowo dupe lowo awon onkowe
ati wipe ki o se itoka si cec.vcn.bc.ca/cmp/

 Titele ipa ona ti o ni atako ti o kere julo ni o mu gbogbo odo ati die ninu awon okunrin wo


© Asekiko 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Oniru Ayelujara nipa Lourdes Sada
––»«––
imodoju iwon kehin: 2015.01.08

 Oju Iwe Kini