Oju Iwe Kini
 Bibere


Ogbufo

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
Български език
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Euskara
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
Igbo
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
한국어 / hangugeo
بهاس ملايو / Bahasa Melayu
Português
Română
Русский
Српски / Srpski
>తెలుగు /Telugu
ไทย / Thai
Türkçe
اردو / Urdu
Èdè Yorùbá

                                        

Awon Oju Iwe miran:

Modulu

Aworan Aaye

Koko

Olubasoro

Awon Iwe Ase ti o Wulo

Ijapo ti O wulo

Eko nipa eda eniyan ati asa re

IGBEGA IMO

Lai se Igbega Ireti

nipa Phil Bartle, PhD

Itumo nipase OLUTUNMBI, Tobi


Iwe Idanileko

Yan Ona ti o laapon ti o lodi si Isebi ti ko to

Leyin igba ti o ba ti se imura sile tan, ti o si ti gba iwe ase lowo awon alakoso, o to asiko fun o lati ran awujo re lowo lati igbese.

Wa bere eyi nipa pipe fun ipade itagbangba pelu gbogbo awon eniyan ni awujo na. Eyi ni yio bere "igbega imo" ninu ayika

O le ri ifarahan wipe awon kan nifesi lati wa si ipade yii. Yala pe okunrin yio wa ti won a si lero wipe ki obinrin ma wa. Ise tire ni lati ri wipe awon obinrin wa

ba kan na ni pelu awon eniyan miran ti nilo ka se iwuri fun: awon odo, awon abirun, awon eya kekeke, awon ti o n ti ju, awon ti esin wo ko wopo, awon ti ko kawe, awon alaini ati awon ti a ti reje

Nigba ti o ba bere si ni b'awon soro nipa isoro ti o wa ni awujo won, ti o ba si n bere eyi ti o se pataki julo ninu isoro won, nibe ni ifarahan yi o je yo wipe won lero pe o fe tan isoro won ni. O gbodo gbe igbese lati se lodi si ero okan won ati lati se alaye fun won wipe awon ni yio yanju isoro won; iranlowo ati ito ni sona nikan ni iwo le se, ki se ki o ba won se.

Bakana, won le lero wipe iwo ni wa pese o hun elo. ni kia kia ati ni idurosinsin pa ero yii mo le, se alaye fun won wipe awon ni o gbodo toka si ati pese fun aini ara won; iranlowo ati itonisona ni o le se fun won

Wa ko lati se amu lo itan, owe ati awon afijo ti o se akawe koko oro re. Ikan lara won ni: "Ma se bere low maalu wipe ki o fun o leyin;ma se bere lowo edie wipe ki o fun o ni wara

O wa ni be lati se pese idanileko isakoso ati iwuri: o si nibe lati pese owo, oniho tabi ohun elo orule

Ma gbagbo wipe awon eniyan o ni ni lero. Won a ro

O gbodo giyanju ni ona ti o laapon lati tako awon ero ti yi o fun won ireti eke won yii ni gban gba (wipe o n pese iranwo). Ti o ko ba se eyi, wa do ju ko iparun ti o mofo lai pe ti yio ba gbogbo ise ti o ti se je. Awon eniyan yio so wipe o se ileri fun won pe iranwo wa sugbon o ku na lati mu ileri re se

Nitoribe ti o ba fe se igbega imo,ni gba na, imo nipa ki ni?

Ranti wipe afojusun tire ya to si afojusun awujo

Won le fe Omi ero, ile iwosan, ile-iwe ta bi ona

Iwo fe ki awujo na la gbara lati le da duro, lati din osi ku, se alekun iwa iwon tun won si, imudara si ise ijoba. Imo ti o fe gbe ga ni wipe, ibi yoowu ki aujo na to si to, ifiyesi lati yan ju isoro, lati lagbara si. Gbogbo nkan ti o nilo ni ife lati se be e, ati idanileko iseakoso ti o le pese

Pipese alaaye deede se pataki (ya go fun igbega ireti eke)

––»«––
Ti o ba se edaa iwe lati ori aaye yi, jowo dupe lowo awon onkowe
ati wipe ki o se itoka si cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Asekiko 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Oniru Ayelujara nipa Lourdes Sada
––»«––
imudoju iwon kehin: 2015.02.16

 Oju Iwe Kini

 Sise Ibeere