Oju Ewe Ibere
Awon Eda

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
বাংলা / Baṅla
Български език
Català
Cebuano / Sugboanon
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Euskara
Ewe
فارسی / Fārsī
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
ગુજરાતી / Gujarātī
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kinyarwanda
Kiswahili
بهاس ملايو / Bahasa Melayu
Polszczyzna
Português
ਪੰਜਾਬੀ / Pañjābī
Română
Русский
सिन्धी / Sindhi
Af Soomaali
తెలుగు /Telugu
ไทย / Thai
Tiếng Việt
Türkçe
اردو / Urdu
Èdè Yorùbá

                                        

Awon oju iwe miran

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo


GBIGBARADI

Atona fun oluse koriya

Nipase Phil Bartle, Ojogbon

Ti a gbifo re lati owo o Adebunmi Adetona Amos


Oro akoso fun Ipele

Awon iwe ti a fi kun eleyi Gbigbaradi Ipele ipele

Mimu ara re sile gege bii oluse koriya fun adugbo

O nilo lati gbaradi ki o to le se aseyege lori ojuse riranrenilowo ni awujo

O gbodo da o loju, o si gbodo ni oye lori awon ete; o gbodo mo nipa adugbo ti o fi oju sun; o gbod ni imo ti a nilo; agbekale re gbodo ye o yeke yeke awon ero nipa rirunisoke.

Ohun agbese akoko ni lati bere iwe atigbadegba.

Iwe ajako awon omo ile-iwe ti owo ko won ti dara.

O le wu o lati lati lo iwe ajako merin ki o si pe akole okookan ninu won ni: (1) Awon ete ati awon ero; (2) Adugbo ti a fi ojusun; (3) Awon ogbon irunisoke, ati (4) Iwe Akosile Awon Ohun ti Se Ni Ojoojumo.

Iru ona eyikeyi ti o wu ki a gba lati murasile, o se pataki ki a tete bere si se akosile bayi.

Se akosile aropo oro pelu eniti yoo kaa ni okan re.

Ipele yi ni o nso fun o nipa awon ohun ti o nilo lati gbaradi. Sugbon mase lero wipe o le se imurasile tan ni 'eekan gban an'

Awa gege bii oluse koriya n ko eko lojoojumo siwaju ati siwaju si nipa awon ohun ti a ti menuba ni ori yii.

O je ohun ti ko ni ipari, ati pe a o ni ijakule ti a ba gba ero pe a ti mo ohun gbogbo ti a nilo lati mo laaye.

––»«––

Ipele Ikoni Kan:


Ipele Ikoni Kan

Ti o ba se adako ohun kan lati oju ewe yi, jowo gboriyin fun eniti (tabi awon ti) wo koo
ki o si wa tun pada da ori re si cec.vcn.bc.ca/cmp/

 Following the path of least resistance makes all rivers and some men crooked


© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2015.01.08

 Oju Ewe Akoko