Afermer xa
Dzadzrado


Gormerderderwo:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
বাংলা / Baṅla
Català
Deutsch
English
Ελληνικά / Elliniká
Español
Euskara
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Italiano
日本語 / Nihongo
بهاس ملايو / Bahasa Melayu
Português
Română
Af Soomaali
తెలుగు /Telugu
Srpski
Tiếng Việt
Türkçe
Èdè Yorùbá
中文 / Zhōngwén

                                        

axa bubuwos:

Dodowo

Lifo

Nyatiwo

Amenkuta

Hahia Gbalerviwo

Kperkperdenu Teferwo


Links to words that begin with:

  A   B   C   D   E   F   G   H   I   J   K   L   M   N   O   P   Q   R   S   T   U   V   W   X   Y   Z


AWON KOKO ORO FUN IPELE "GBIGBARADI"

nunlorla Phil Bartle

nugormerderla Victor Tsikpe-Morttey

IBINU

Eyi ti o se e se ki o lewu ju ninu imolara wa ninu ise wa na a ni ibinu –– Bi a se le se amojuto re.  Gege bi aniyan, a ni awon imolara kan, ati pe ibinu je okan ninu won. O kuku dara bi eniyan ba binu; ara pe a je eniyan eleran ara naa ni. Ko ye ki a ni idalebi okan tabi ki oju ki o ti wa nigbati a ba ni imolara ibinu. Ibinu fun ra re je okan ninu ihuwasi omo eniyan. A gbodo tewo gbaa nigba ti a ba n binu.

Sugbon sa, ihuwasi wa nigba ti a ba n binu le ko ipa lori ise wa, boya a nse koriya fun awon adugbo ni, a nse adari awon ti o fi ara won jin tabi a nse amojuto awon osise. Nigba ti onibara kan, eni-ti-o-fi-ara-re-jin, osise tabi enikan ni adugbo ba se asise, paapaa iru eyi ti o nipa lori afojusun wa, fun apaere, o see se ki a fe fi ibunu han. Sugbon akokoyi gan an ni o ye ki a fi owo wo inu ki a si fi ara bale.

Nigba ti a ba ri enikan ti o se asise ti o nipa lori abayori ti o wu wa, a nilo lati se idamo pe bi a ti n rii n bi wa ninu ati pe ojuse wa ni lati se amojuto iru ibinu bee. Ohun ti o dara ju ti a le se lesekese ni pe ki a jade lati rin kaakiri. Ti a ko ba ni akoko ti o le to fun eyi, a gbodo jade lo si inu yara miran lai fi ibinu wa han rara titi ti inu wa yio fi ro lasepe a je ki awon ti o mu inu bi wa ko firi pe inu bi wa rara

Lehin naa, nigba ti a ba ti fi ibinu wa si abe akoso, a wa le se amojuto ohun ti o mu ki ibinu wa ki o ru soke. Ti o ba se pe okan ninu awon onibara wa ni ose asise tabi eni-ti-o-fi-ara-re-jin, tabi osise, tabi enikan ni adugbo, a le se gegebi a ti se apejuwe ninu awon koko oro, Asise. Igbese yen yio mun-ina-doko nigba ti o ba je pe ibinu wa ti lo sile, ara wa ti bale, a si ti wa ni alafia nigbati a gbee.

 العربيّة: غضب  বাংলা : রাগ  Català: ràbia,  Deutsch: wut  Ελληνικά: Θυμός  English: anger, ire, choler,  Español: Ira  Euskera: Haserrea  Ewe: ibinu,  Filipino/Tagalog: Galit  Français: colère  Galego: anoxo  Italiano: collera  日本語: 怒り  Kiswahili: hasira  Malay: Kemarahan  Português: ira  Română: furie  తెలుగు: ఆవేశము  Tiên Việt: sự tức giận

 

IWARA PAPA

Awon igba miran a ma n pe ni iwara pap ti iba ara eni gbe ni awujo, Lati inu oro ede Giriki 'anima' (aye, okan, ina, isipo pada ti a ko sese ronu si). Lati le ran lowo tabi se koriya fun awujo ki o le fun rare te siwaju, ko o le wa laaye, ki o le dagba soke.

Awon igba miran a ma n lo gege bi oro aropo fun sise koriya. Oro ti a pe ni iwara papa (animation) tumo si pe ki a ran awujo kan lowo lati fi o fi owo-so-wo-po ki ori won ki o si ya lati le se ohun ti o dara ti won fe se

Ogbon ise fun Imunlokun Awujo tun mun iwara papa larin awujo te siwaju ni ipele kan si nipa lilo awon ogbon ikoni lati tun fi kun ipa awujo, tabi awon elegbejegbe ti o wa ni awujo, lati pinun, se eto, ati lati se amojuto nipa eto fun idagbasoke awujo won. O ma n se idanileko fun awon eniyan ati awon olori ni awujo lori ati se eto lati se ikawo idagbasoke awujo fun ra re.

Beni o tun ma a n ru awon osise ijoba, awon alakoso ni agbegbe, ati awon adari ni awujo soke, ti o si n ko won lati yo owo kuro ninu ojuse bi i 'baba keresi' ti o n pese ohun elo a mun-aye-derun. Won n ko lati fi ona han awon eniyan ni awujo bi a ti n se idamo awon alumoni ti a ni ati lati gbe igbese lati pese ati lati se itoju awon ohun elo a mun-aye-derun fun ibugbe awon aniyan.

العربيّة: تنشيط  বাংলা: অনুপ্রেরণা  Deutsch: animation, Soziale Animation  Ελληνικά: κοινωνική ζωοδότηση  English: animation, social animation  Español: animación social  Euskera: animazioa  Ewe: iwara papa,  Filipino/Tagalog: pagbibigay-buhay panlipunan  Français: animation, animation sociale  Galego: animación  हिन्दी: एनिमेशन  Italiano: animazione  日本語: 活発化, 社会活発化  Kiswahili: ramsa  Malay: animasi  Português: animação social, animação  Pyccкий: oсведомленность  Română: animare sociala  Tiên Việt: sự nhiệt tình

 

ENI TI O NI IWARA PAPA

Oluse koriya. Wo: iwara papa.

العربيّة: العربية,  বাংলা: অনুপ্রেরক,  Català: animador,  Deutch: animator  Ελληνικά: ζωοδότης, κινητοποιητής  English: animator,mobilizer, activist  Español: activista  Euskera: animatzailea  Ewe: eni ti o ni iwara papa,  Filipino/Tagalog: tagapagpakilos  Français: mobilisateur, animateur  Galego: animador  Italiano: animatore  日本語: 訓練士  Kiswahili: ramsisha  Malay: penganimasi  Português: animador  Română: animator  Tiên Việt: người nhiệt tình

 

AIKO IBI ARA SI NKAN

Aiko ibi ara si nkan je okan ninu ohun marun gbogi okunfa osi ati aile da ara eni mojuto.

Ni awon igba miran o ma ni se pule awon ero tabi igbekale ti o ni ewu.  Sibe, "Gbadura si Olorun, sugbon si tera mo oko titu de eti odo," ni owe awon ara Russia kan ti o n, se afihan otito na a pe, bi o tile je pe owo Olorun ni a wa, sibe a ni ojuse lati ran ara wa lowo.

Opolopo ipa ise ni a da mo wa: lati yan, lati fi owo so owo po, lati se eto bi igbe aye gbadun wa yio se dara sii; a ko gbodo lo ero wa nipa Olorun tabi Allah gege bii ohun ikewo lati ma se ohun kankan.

العربيّة: العربيّة,  বাংলা: উদাসীনতা,  Català: apatia,  Deutsch: Apathie,  Ελληνικά: απάθεια,  English: apathy,  Español: apatía,  Euskera: apatia,  Ewe: aiko ibi ara si nkan,  Filipino/Tagalog: pagsasawalang bahala,  Français: apathie,  Galego: apatía,  Italiano: apatia,  日本語: 無関心,  Kiswahili: usugu,  Malay: apati,  Português: apatia,  Română: apatie,  Somali: naceyb,  Tiên Việt: sự thờ ơ

 

IPA

Ogbon ise, agbaratabi okun ti awujo tabi agbri-jo- po kan. Nigbati a ba kun un ni owo, o ma n ni okun sii.

العربيّة: قدرة,  বাংলা : সক্ষমতাঃ,  Català: capacitat,  Deutsch: Macht, empowerment, die stärkung, leistungsfähigkeit,  Ελληνικά: δυνατότητες, ισχύς, δύναμη,  English: capacity, power, strength,  Español: capacidad, potenciación,  Euskera: gaitasuna,  Ewe: ipa,  Filipino/Tagalog: kakayahan, pagpapalakas,  Français: capacité, empowerment,  Galego: capacidade,  हिन्दी (Hindi): क्षमता,  Italiano: empowerment,  日本語: 容量, 強くする,  Kiswahili: uwezo,  Malay: kapasiti,  Português: capacidade, fortalecendo,  Română: capacitate,  Pyccкий: paзвития,  Somali: awooda,  Tiên Việt: năng lực, tăng cường

 

SISE AWARI IPA ENI

Sise afikun fun " ipa" (ogbon ise)kan tabi agbari-jo-po kan(elegbe-je-gbe). Ikun-ni-lagbra. Ifun-ni-lokun

Wo Awon eroja fun Okun fun akojopo awon ohun merin-din-ni-ogun ti o je eroja fun mimu ki ipa eni dagba sii.

Iyato ti o wa laarin sise awari ipa eni ati mimu ipa eni dagba sii wa da lori ibi ti okun fun idagbasoke ti wa.

Oro ti a pe ni "mimu -ipa-eni dagba sii" tumo si pe awon ajo kan lati ode awujo naa tabi agbari-jo-po kan ni yio se agbateru eto lati mu ki ipa awujo tabi agbari-jo-po bee dagba si.

Ohun ti o bi eleyi ni ero ti o da lorii " bi a ti se eto ki awujo le dar sii."

Ni idakeji, oro ti a pe ni "sise awari ipa eni" tumo si pe agbara fun idagba soke ninu awujo bee wa ni inu awujo tabi agbari-jo-po bee.

Wo oro Julius Nyerere, nigba ti o so pe; awujo tikalarare ni ma n mu ara re dagba soke.

 

AJOYO

Akoko ajoyo je akoko ti a nse akiyesi isele kan ti o mu ayipada ba aye enikan tabi ti ohun kan. O je akoko fun aweje-wemu itagbangba.

Fun oluse koriya, sise ajoyo pe a se aseyori lori ise ti a da owo le ni awujo je okan ninu awon eroja pataki lati fun awujo lokun. Ni akoko yi ni a n se igboriyin ita gbangba pe awon agbarijopo awon eniyan ni awujo lowo si idagbasoke nipa riran ara eni lowo.

O tun je akoko ti a ni ore ofe lati bere ni akotun; ani gbigbe dide eto sise koriya leekan si.

Wo Sise Koriya . Wo Ajoyo.

العربيّة : الاحتفال,  বাংলা : উদ্‌যাপন,  Deutsch: feier,  Ελληνικά: Εορτασμός,  English: celebration,  Español: celebración,  Euskera: ospakizuna,  Ewe: ajoyo,  Filipino/Tagalog: pagdiriwang,  Français: célébration,  Galego: celebración,  日本語: お祝い,  Kiswahili: sherehe,  Malay: keraian,  Português: celebração,  Română: celebrare,  Pyccкий: Празднование,  Tiên Việt: sự khen ngợi  ردو: جشن

 

AANU SISE

Sise iranlowo fun awon eniyan ti o se alaini tabi ti o nilo iranlowo je ohun ti o kari aye, beeni a ri ipe fun sise eyi ninu iwe gbogbo esin ti o se pataki ni gbogbo agbaye. Sugbon fifi fun ni je orisirisi.

Bi ebun ti a fun enikan ba mun ki eniti a fi fun di eni ti ko le da mu oju to ara re mo afi ki o gbara le o, o ko se iranlowo lati fun iru eniyan bee ni okun, tabi ran an lowo lati di eni ti o dagba to oju bo.

Bi a ba fun alagbe kan ni owo ni jo popona, ohun ti a kan n se ni pe fun un ni idanileko bi iru eni be yio se je alagbe sii.

Bi a ba ro arojinle lori ise iranlowo ti a ba n se, ti o ba si ran iru eniti a n ran lowo lati ni okun sii (wo itan Momodu ati okun ni ipele Awon itan), nigba naa iru ebun bee yio je eyi ti o wulo gidigidi.

العربيّة:صدقة,  বাংলা : বদান্যতা,  Deutsch: Wohltätigkeit,  Ελληνικά: φιλανθρωπία,  English: charity,  Español: caridad,  Euskera: karitatea,  Ewe: aanu sise,  Filipino/Tagalog: kawang-gawa,  Français: charité,  Galego: caridade,  Italiano: carità,  日本語: 慈善,  Kiswahili: kujitolea,  Malay: amal,  Português: caridade,  Română: caritate,  Tiên Việt: lòng nhân từ

 

AWUJO

Opolopo ona ni a ti gba lo oro ti a pe ni "awujo".

Awon oni imo ijinle nipa eda so pe itumo oro ti a pe ni awujo ni opolopo awon eniyan ninu iru eda kookan,tabi oniruuru eda ti o yato, ti o wa laaye, ti o n fi aga gba ga, ti o n fi owo so owo ki o le wa ni odindi ti o gbooro.

Lati igba ti ti ero aye-lu-ja-ra [internet] ati imo nipa iba ara-eni-soro [information technology], opolopo agbarijopo awon eniyan, ti won ni inu didun sii ni won n po sii laisi gbedeke aala ti won si n ba ara won soro nipase ero naa.

Afojusun wa ni inu awon ipele idani-leko lati ori ero aye lu jara yi, ni o da lori itumo awujo si ohun ti a jin le pupo, awujo ti awon alaaye n gbe, eyi ti o ni gbedeke ibi ti ile re fe de (a le fi kun eleyi nigba ti a ba n soro awon eniyan bii awon ti o n da eran kiri), won wa ni ibasepo, fun apere, ni awujo ti ti o bere lati bii awon aladugbo ni awon ilu nla, titi o fi de awon abuleko ti o jinan rere. Wo Awon olugbe ori ile.

Awujo kii se akojopo awon eniyan olorijori lasan. O je ohun ti o ni emi ti o si ni ibasepo pelu asa, o je akojopo ibasepo larin awon eniyan, gbogbo ohun ti eniyan le ko ni eko. Ipa mefa ti o pin si ni: imo ero, oro aje, agbara oselu, iba-ara-eni gbe po, awon ohun ti a jo gbe ni aruge papo, igbagbo ati ero. Nipa eko kiko nikan ni a se le ni oye awon nkan wonyi.

Gege bii igi tabi ohun ti o ni iye ninu miran, bi awon eniyan ti se n da ara po mo awujo, be naa ni awon kan n fii sile nipa iku tabi omo bibi, tabi fifi adugbo yen sile lo si ibi miran. Sibe iru awujo bee ko ye wa ni aye ti o si ndagba sii. Ko si ni isokan patapata ri, nitori pe o ni opolopo eya, ifagagbaga, idije, ati itaporogan ni arin re. Ohun ti a n pe ni awujo po ju apao eyo kookan ninu awon ohun ti o wa ninu re. Wo " Ki ni a n pe ni awujo."

Wo:  Awon Abuda Awujo.

العربيّة:مجتمع محلّي,  বাংলা : জনগোষ্ঠি,  Deutsch: gemeinde,  Ελληνικά: κοινότητα,  English: community,  Español: comunidad,  Euskera: komunitatea,  Ewe: awujo,  Filipino/Tagalog: komunidad,  Français: communauté,  Galego: comunidade,  Italiano: comunità,  日本語: 共同体,  Kiswahili: jamii,  Malay: komuniti,  Português: comunidade,  Pyccкий: Cooобщество,  Română: comunitate,  Somali: bulsho,  Tiên Việt: cộng đồng

 

AWON OHUN TI O DA LORI AWUJO

Ki is tabi agbarijopo to le da lori awujo, o gbodo je eyi ti gbongbo re wa ni iru awujo bee,olugbe awujo bee ni ojuse be si ni awon ipinu ati eto nibe gbodo je eyi ti awon ulogbe awujo bee fi enu ko si.

A komle so pe ise kan tabi iranlowo lati ode iru awujo bee je eyi ti o da lori awujo yen.Bee si ni, a ko le so pe tori a gba imoran lowo awon olori ni awujo kan ni o le je ki iru ise beeje eyi ti o da lori awujo.

Iyato nla ni o wa larin ise ti o da lori awujo ati eyi ti a kan se si iru awujo be. Ti ile ise kn ba da ise kale ni awujo kan ( fun apere, ile iwosan, tabi iru eto miran), o je eyi ti a kan da si awujo be ni.

Ti yio ba je eyi ti o da lori wujo nitooto, akitiyan, kiko ile, ise, tabi apejopo, gbodo je eyi ti a yan, mu, ti a si dari lati owo awon gbogbo gboo eniyan ni iru awujo bee(kii kan se awon eka kan). Ohun ti o se pataki ni ki o je pe inu awujo bee ni a ti nse gbogbo ipinu.

Wo Ise Iranlowo Awujo ni awon Ibudo Awon Eniyan ti ko ni Ile.

العربيّة ائم على المجت مع المحلّي,  বাংলা : জনগোষ্ঠি ভিত্তিক,  Deutsch: gemeindenah,  Ελληνικά: βασισμένο στην κοινότητα,  English: community based,  Español: basado en la comunidad,  Euskera: komunitatean oinarritutako,  Ewe: awon ohun ti o da lori awujo,  Filipino/Tagalog: batay sa komunidad.  Français: fondé sur la communauté,  Galego: baseado na comunidade,  日本語: 共同体を基盤とする,  Italiano: community based,  Kiswahili: ilyo ya jamii,  Malay: berasaskan komuniti,  Português: baseado na comunidade,  Română: ancorata in comunitate,  Tiên Việt: nền tảng, cơ sở của cộng đồng

 

APEJOPO TI O DA LORI AWUJO

Apejopo ti o da lori awujo (CBO) ni awon apejopo ti a da ti o si dagba larin awujo, ni ibi ti awon eto ati igbese ti o siwaju ipinu sise ma tiowo awon olugbe inu awujo bee wa agbajopo awon eniyan.

Ile ise ti a da sile ti a si n se akoso ati awon ipinu re lati ode awujo le je eyi ti o wa ni arin awujo sugbon ko da lori awujo. Wo adape oro ti pe ni, CBO.

 

ISODI TITUN TI O DA LORI AWUJO

Ohun ti Isodi titun, nihin, tumon si ni nipa ti ara (ni ti ibi), imolara tabi ni ti opolo awon eniyan ti ara won ko da pe ni ona an tabi omiran.

Ni ibi ti isodi titun yi ba ti da lori awujo, sise ipinu ati ojuse fun iranlowo awon akanda eda ti o wa ni iru awujo bee yio wa lati inu awujo, kii se lati ode re.

Wo adape oro ti a pe ni, CBR.

 

IGBON OWOSI LATI ODO AWON OLUGBE AWUJO

Nigba ti a ba n te enu mo pe igbon owo si kii si ohun kan naa pelu ilowosi (bi o tile je wipe opo eniyan ni o ma n pee ni ohun kan naa), sibe a gbodo kiyesi pe mejeji ni o s pataki.

Nigbati ilowo si awon eniyan ni awujo ninu awon ipinu ti a n se ma n mu ki a so pe iru awon akitiyan bee je eyi ti o da lori awujo, fifi ohun kan tabi omiran sile se pataki lati ri pe awon olugbe adugbo bee ni imolara pe ajoni ni ohun ti a ba gbe se ni iru awujo bee. Ki i se pe won ri gba lofe ni sugbon o na won ni ohun kan.

Imoran ti agba ni pe, o kere tan, ida kan ninu ohun meji ti a nilo fun ise ni awujo ti a n ran lowo ni o gbodo wa lati inu awujo bee fun ra re. Ni akoko, awon olugbe awujo le ma wo iru eto yi pelu ibu- bojo. Sugbon alaye ti ao se ni pe o ye ki a se iwadi iye ti ise afara-se awon eniyan ni awujo paapaa ku si. Iya lenu ni yio je nigba ti won ba se awari pe ilowosi won je eyi ni o ni iye lori pupo.

A o tun fi han won pe akoko ti awon eniyan n lo, paapaa julo, awon ti o wa ni awon igbimo alase, ti won n se ipinnu tabi se eto lori awon ise sise, je akoko ti o ni iye lori pupo. O ye ki a se idi-ye-le fun ise afara-se. Bee ni a o tun se alaye pe opolopo igba ni o je pe a ma n din iye ti yan ati idoti ti awon eniyan ba fi sile ku. o si ye ki a fun won ni ojulowo iye ti won ba je ni, gegebi ilowo si awon olugbe awujo.

العربيّة:مساهمة المجتمع المحلّي,  বাংলা : জনগোষ্ঠির অংশপ্রদান,  Deutsch: gemeindebeitrag,  Ελληνικά: κοινοτική συνεισφορά,  English: community contribution,  Español: contribución comunitaria,  Euskera: komunitatearen ekarpena,  Ewe: igbon owosi lati odo awon olugbe awujo,  Filipino/Tagalog: kontribusyon ng komunidad,  Français: contribution de la communauté,  Galego: contribución comunitaria,  Italiano: contributo della comunità,  日本語: 共同体の貢献,  Kiswahili: mchango wa jamii,  Malay: sumbangan komuniti,  Português: contribuição da comunidade,  Română: contributia comunitatii,  Tiên Việt: sự góp phần cho cộng đồng

 

IDAGBASOKE AWUJO

Nigba ti awujo ba ndagba soke, o ma n po si. Wo oro ti a pe ni, Idagbasoke. Ko se dandan ki o tumo si pe o n tobi sii tabi o n ni oro sii. Ohun ti o tumo si ni pe o n dagba sii, o si n ni okun sii.

Niwon igbati a ko ni so pe ododo ti a fatu ti ga si lehin ti a faa tu, bee na ni oluse koriya nikan ko le mu ki awujo dagbasoke. Awoju fun ara re [gege bi ibugbe awon eniyan] ni yio mun ara re dagbasokeOhun ti o le se ko ju ki o gba ni ni iyanju, se atilehin fun ati se itona fun awon olugbe ni awujo .

Awon eniyan kan ti ro pe ti a ba so wipe awujo ndagba soke sii, ohun ti o tumo si ni wipe o ti n di oloro sii –– anikun lori iye owo ti olorijori nri. O seese ki o ri bee, sugbon, o ju bee lo.

Iyipada ni, ni akoko ti awujo n te siwaju, ti awon ohun rere n po sii, ti agbara agba-ri-jo-po n poo si, ti awon ayipada rere si n po si.

Idagbasoke tumo si didagba ni gbogbo origun mefa ti asa ni.  O yato si pe a n fun awujo ni okun sii. Bi o tile je pe alaye lori awon mejeji yato si ara won, sugbon won ni ibasepo daada.

العربيّة:تطوير المجتمع المحلّي,  বাংলা : জনগোষ্ঠি উন্নয়ন,  Deutsch: gemeindeentwicklung,  English: community development,  Español: desarrollo comunitario,  Euskera: komunitatearen garapena,  Ewe: idagbasoke awujo,  Filipino/Tagalog: kalinagangg (kaunlaran) pangkomunidad,  Français: développement de la communauté,  Galego: desenvolvemento comunitario,  Italiano: sviluppo della comunità,  日本語: 共同体の発展,  Kiswahili: maendeleo ya jamii,  Malay: pembangunan komuniti,  Português: desenvolvimento da comunidade,  Română: dezvoltarea comunitatii,  Somali: horumarka bulshada,  Tiên Việt: sự phát triển của cộng đồng

 

IFUN AWUJO LOKUN

Lati kun awujo kan ni ipa lati dagba sii ninu ipa re lati ran ara re lowo.

O ju pe a kan n se afikun awon ise tabi eto a mun aye derun bii ona, imototo, omi, eto si iwe kika, ati itoju alaisan.

O tumo si okun sii ati agbara sii. O tumo si ogbon ise sii, ida ara eni loju sii, ati imu-na-doko sii ninu eto sise. A ko le se ala-ba-pade-re nipa pe a n da awon ohun elo jo lati odo awon alejo. O seese ki o di aseyoyi nipa awon ise sise ni awujo. Sugbon aleyi yio seese nigba ti gbogb awon eniyan ni iru awujo bee ba lowo sii lati ibere, lati se ipinnu lori ohun ti a o se, lati se awari awon alumoni ti o fi ara sin ni iru awujo bee, ati nipa riri awon ohun elo bii ohun ajo-ni lati ibere titi de opin.

Bi o tile je pe ijoba le se iranwo lati mu ki eto iselu ki o gbooro sii, nipa sise awon ofin ti yio fun awujo ni okun. Sugbon ipa lati se amulo awon ipinu to o da lori ofin yio duro lorii ipa ise. ani agbara lati se ipinu nipa eto idagba-soke ara re, se ipinu nipa ojo iwaju re. Agbara, okun, ipa, ipa ise, ifun-ni-lokun.

Idagbasoke sii awujo tumo si ki awujo o ma a dagba sii ni gbogbo agbegbe mefa ti asa.  O yato si ifun awujo lokun ti o tumo si pe ki o ma ni okun sii. Bi o tile je pe iyato wa larin itumo awon oro mejeji, sibe won ni afiwe ti o so won po.

العربيّة:تمكين المجتمع,  বাংলা : জনগোষ্ঠির ক্ষমতায়ন,  Deutsch: gemeindestärkung,  English: community empowerment,  Español: potenciación comunitaria,  Euskera: komunitatea sendotzea,  Ewe: ifun awujo lokun,  Filipino/Tagalog: pagsasakapangyarihan ng komunidad,  Français: fortifier de la communauté,  Galego: potenciación comunitaria,  Italiano: empowerment della comunità,  日本語: 共同体強化,  Malay: pemberdayaan komuniti,  Português: fortalecendo da comunidade,  Română: consolidarea coomunitatii,  Tiên Việt: sự uỷ quyền cộng đồng

 

IDANILEKO LORI SISE AKOSO AWUJO

Awujo idanileko lori sise akoso ni a da oju re ko ona lati din ise ati osi ku, ona lati kun awon ti owo oya won ko po ni awujo lowo nipa sise eto ati akoso awon ohun ini, awon ikole, ise sise ati eto atunse. Iru idanileko yi kii kan se fun lati ko awon eniyan ni ogbon ise nikan tabi lati se ito-ni-leti fun awon olorijori, sugbon fun ogbon amuse.

Idanileko, gegebi ona lati fun awonawujo ti owo oya won kere ni okun sii, lati din ise ati osi ku, lati se iwuri fun fun ilowo si awon eniyan, gege bi iran lowo fun eto iselu ti o mu-na-doko, kuro ni ohun ti a le pe ni eto lati se ito-ni-leti ati lati se iranlowo fun ogbon ise fun awon akeko. O tun ni ise koriya ati ise akoso. Eyi kii se idanileko ti o wopo.

Lati se agbekale iru idanileko yi ni ona ti o wopo ni lati je ki a ni ewu aile ko ni daradara, lati se igbe-laru-ge fun ogbon ise dipo igbani ni iyanju, sise koriya ati eto ninu eko kiko.

idanileko lori sise akoso ni ona ti a n se yi ni a se eto re lati kun imu-na-doko awon alakoso ti o wa ni oke patapata ati ni arin ni awon ile ise okoowo.

A ti se atunse re nihin, a si ti se amunlo ogbo lati ko awon osise jo; ni pataki lati se koriya fun ati lati fi okun si fun awon eniyan ni awujo ti owo oya won kere lati wa papo, ki won se iranlowo fun ara won, pelu erongba lati yi awujo pada si rere.

 

ILOWOSI AWUJO

Oro ti a pe ni Ilowosi laarin awujo ju pe a kan da si ise sise, tabi a fi ohun kan sile: o ni se pule pe ki a da si ipinu sise, lati yan iru ise ti a o se ni arin awujo, lati se eto fun, mu oju to sise re, se amojuto re, ati sise idari re. O yato si pe a kan lowo si ati se ikojo ni arin awujo.

Sise Iwuri fun Awon Eniyan ni Awujo. O ma n se iwuri fun akitiyan awon eniyan ni awujo ti a fi oju sun, pelu erongba pe ki awon eniyan o ko ipa ti o ni laari lori oro idagbasoke adugbo won. Eyi yio bere nigba ti won ba ni owo ninu ipinu lati da owo le ise kan, tabi lati se koriya ti yio mu ki awon eniyan o se ikojo alumoni ti won nilo ki won o si tun se eto bi awon akitiyan won yio se lo.

Ilowosi ni awujo ma n se iwuri llati ri pe gbogbo eniyan (kii se die ninu won tabi awon ara ita) ni o ni owo ninu ipinu sise ni awujo.

Nipa iru ogbon ise yi, a nse iwuri fun awon eniyan ni awujo, nitoripe ohun ti a ko ba je iya fun kii le to ojo. Bee pelu, a tun maa n gba ijoba tabi awon oluranlowo lati ode, ki won o ni apero pelu awon eniyan ni awujo nipa ohun ti won fe se; eyi ni a n pe ni fifi ikun lu ikun pelu awon olugbe awujo.

Ilowosi ni awujo ti a n se alaye re nihin kii se ohun kan naa pelu pe ki a se iko owojo tabi tabi pe a kan se fifi ikun lu ikun pelu awon eniyan ( eyi ti o wopo larin opo awon ile ise ti o n se iranlowo fun awon eniyan). Ilowo si nihin, tumo si ki a lowo si ipinu sise, idari ati sise amojuto.

العربيّة:مشاركة المجتم المحلّي,  বাংলা : জনগোষ্ঠির অংশগ্রহন,  Deutsch: gemeindepartizipation,  English: community participation,  Español: participación comunitaria,  Euskera: komunitatearen parte-hartzea,  Ewe: ilowosi awujo,  Filipino/Tagalog: Pakikilahok ng Komunidad,  Français: participation de la communauté,  Galego: participación comunitaria,  Italiano: partecipazione della comunità,  日本語: 共同体の参加,  Kiswahili: Ushiriki wa jamii,  Malay: penyertaaan komuniti,  Português: participação da comunidade,  Română: participarea comunitatii,  Somali: ka geyb galka bushada a,  Tiên Việt: sự tham gia của cộng đồng

 

IFI IKUN LU IKUN

Nigba ti ile ise kan ti o n se iranlowo fun awon eniyan ba lo lati se ifi ikun lu lu ikun pelu awon olori ni awujo kan, opo igba ni won ma n beere boya iru awujo be n fe ki a se agbakale ise kan fun won. Idan ti o si wopo ni "beeni"  Iru ile ise bee yio wa pada lo so fun awon alakoso ile ise won pe awon eniyan kopa ninu ipinu sise. Eyi ko si ri be.

Ohun ti won kan se ni lati se ifi ikun lu ikun, kii se pe awon eniyan ni awujo ni owo si iru ipinu be, tabi ki won o yan lati se eto fun ise kan laarin awon ohun ti o kan awujo yen gbon-gbon (yato si eyi ti o kan iru ile ise ti o fe se iranlowo fun won).

العربيّة:يستشير,  বাংলা : পরামর্শ গ্রহন,  Deutsch: beraten,  English: consult,  Español: consultar,  Euskera: aholkatu,  Ewe: ifi ikun lu ikun,  Filipino/Tagalog: konsulta,  Français: consulter,  Galego: consulta,  Italiano: consultazione,  Kiswahili: tatufa ushauri,  Malay: berunding,  Português: consulte,  Română: consultare,  Tiên Việt: tham khảo

 

IDA OWO SI

Awon eniyan kan ko mo iyato ti o wa ni arin ilowosi ati ida owo si. Nigba ti opolopo eniyan ba gbo ohun ti a pe ni ilowosi, se ni won ma n ro pe idawosi ni a n so. Ohun kan ti won ma nro ni ise afi ara se ti awon eniyan yio se.

O se eni ni anu pe opolopo igba ni o ma n je pe a o kan so awon eniya di eru ti a mu ni agadi lati lati si ise tabi lati fi ohun kan tabi omiran sile( boya ile tabi ounje). Atenumo iwe yi yato gede gede.Ilowosi nihin tumo si pe a kipa ninu ipinu sise , kii se pe a kan da awon ohun elo jo. Wo idawo si ni awujo.

العربيّة:مساهمة,  বাংলা : সম্প্রদান,  Deutsch: beitrag,  English: contribution,  Español: contribución,  Euskera: ekarpena,  Ewe: ida owo si,  Filipino/Tagalog: kontribusyon,  Français: contribution,  Galego: contribución,  Italiano: contributo,  Kiswahili: mchango,  Malay: sumbangan,  Română: contributi,  Tiên Việt: sự đóng góp

 

IBANI WI NI ONA TI O LODI

Okan pataki ninu ohun amuns'ogbon ti o ye lati ko ni pe nigba ti a ba ri ohun kan ti o lodi, ki a se ibaniwi ni ona ti o lodi ki i sabaa je eyi ti o to, tabi ona lati se atunse ohun ti o lodi bee. Dipo bee, se ni o maa n mu ki nkan baje sii.

Ki ni idi? Idi ni pe, nigba ti a ba n ba awon eniyan wi, se ni o maa n da bi eniti a gbe ogun ti won, eru a si maa ba won. Iba-ni-wi ni ona ti o lodi maa n mun ki igboya ninu ara eni ati iyi ara eni dinku.  A maa n gbe oju agan si eni ti o ba n ba ni wi ni ona ti o lodi, ati pe, dipo ki a ko eko ki a si se atunse ti o ye, se ni a maa n wa idi fun ohun ti a se.

Ni igba ti a ba n se koriya fun awon awujo, tabi a n se akoso awn ti o fi ara wo jin lati se iranwo, tabi a n se akoso awon osise, a gbodo ko wo oye pe o seese ki won o se asise, ki a si se imunrasile ona lati yanju gbogbo asise bee ti o le wa si aye, ni ona to yio ran awon afojusun wa lowo.

Bi a ba n fi ibinu wa han, ti a si n se ibaniwi eni ti o se asise ni ona ti o lodi, seesi ki o kan je ona ti o rorun lati huwa ni akoko yi, sugbon iye ti a o san fun iru ihawasi yi laipe yio po jojo. Lo wo awon koko oro: Awon Asise, Ibinu, ati Sandwich, ati wiwa ona lati se atunse awon asise ti a se lai je pe a n ba ni wi ni ona ti o lodi.

Wo: Maa Gbe Oriyin Fun ni ni Opolopo Igba.

العربيّة:نقد,  বাংলা : সমালোচনা,  Deutsch: kritik,  English: criticism,  Español: críticas,  Euskera: kritika,  Ewe: ibani wi ni ona ti o lodi,  Filipino/Tagalog: kritisismo o pamumuna,  Français: critique,  Galego: crítica,  Italiano: critica,  Kiswahili: pingamizi,  Malay: kritikan,  Português: crítica,  Română: critica,  Tiên Việt: phê bình

 

ASA

Ju oro orin ati ijo lasan, ohun ti a pe ni asa, ninu ti imo ijinle iba ara eni se, tumo si gbogbo eto iba ara eni gbe po ni arin awujo, akojopo ohun gbogbo ti a ko nipa ikohasi ati ihuwasi,ti o je akojopo asa iba ara eni gbe po ni awujo ti o ni eka mefa: awon ti o ni se pelu imo ero, awon ti o ni se pelu eto oro aje, awon ti o ni se pelu eto oselu, awon ti o ni se pelu bi a se n ba ara eni gbe po, awon ti o ni se pelu awon arojinle wa ati awon ti o ni se pelu iwoye wa nipa agbaye.

okan pataki ninu eka asa ni "apere". Asa kii se ohun ti a bi mo eniyan; fifi awon apere han ni o se alatagba re lati iran kan de omiran. Awon iigba miran, a maa n pe ni "superorganic," nitoripe o n se akojopo awon ohun ti o ju oro ibi lo, tabi eniyan, ti o n se akojopo ati agbateru asa.

Wo "Asa." Awujo ti o ni asa ibile. Wo: Eja Abami. Wo Awon Orisirisi Itumo Asa.

العربيّة:ثقافة,  বাংলা : ংস্কৃতি,  Deutsch: kultur,  English: culture,  Español: cultura,  Euskera: kultura,  Ewe: asa,  Filipino/Tagalog: kultura,  Français: culture,  Italiano: cultura,  Galego: cultura,  Kiswahili: tamaduni,  Malay: budaya,  Português: cultura,  Română: cultura,  Somali: dhaqanka,  Tiên Việt: văn hoá

 

IHUWASI DIDURO DE IRANLOWO SAA

Ihuwasi a n durode iranlowo saa ni ihuwasi ati igbagbo pe agbarijopo awon eniyan kan ko le da yanju isoro ti won ni lai si pe won ri iranlowo gba lati ode.

Fifi-fun-ni lasan a ma mun ki iru iwa yi tun buru sii. Wo: Ihuwasi Diduro de Iranlowo Saa.

العربيّة:متلازمة,  Bahasa Indonesia: dependensi,  বাংলা : পরনির্ভরতা (লক্ষণ),  Deutsch: Abhängigkeit (Syndrom),  Ελληνικά: Εξάρτησης,  English: dependency,  Español: (síndrome de) dependencia,  Euskera: mendekotasuna,  Ewe: ihuwasi diduro de iranlowo saa,  Filipino/Tagalog: pagtangkilik,  Français: syndrome de dépendance,  Italiano: dipendenza,  日本語: 依存,  Malay: ketergantungan,  Nederlands: afhankelijkheid,  Português: síndrome de dependência,  Română: dependenta,  Somali: ku tiirsanaanta,  Tiên Việt: phụ thuộc  ردو (Urdu): محتاجی کی لت,

 

IDAGBASOKE

Opo eniyan ni o ma n ro pe ohun ti idagbasoke tumo si ni pe ki ohun kan po si, sugbon arin gbun-gbun re gan an ni iyipada ti o mu-na-d'oko.

Idagbasoke tumo si lati dagba si, di-da-gba-si ju pe ki ohun kan o kan to sii lo; o tun tumo si pe ki ohun kan o ni opolopo eka sii ki o si ni okun sii.

Nigba ti aujo kan ba ndagba soke, a maa ni okun sii ati eka sii.

A maa ni iyipada ninu eto iba ara eni gbe ni awujo.

Wo "Asa." Si oni imo ijinle lori eto oro aje, idagbasoke ko ju pe ki oro ilu tabi owo oya awon eniyan ki o po sii (boya ti a ba woo ni ti gbogbo eniyan tabi ni ti olori-jori); oni imo nipa ero le ri igbasoke bii ohun ti ko ju pe ki a ni akoso sii lori oro ohun amu-se-agbara, tabi awon ohun elo ti o ja-fafa ti o si ni agbara sii.

Sugbon, fun olusekoriya, eyo meji pere ni awon wonyi laarin awon ona mefa ti asa maa n gba fi ara han ni awujo ti o yi pada. Idagbasoke tumo si ayipada ti o maa n fi ara han ni awujo ni ona mefe ti asa fi maa n fi ara han: imo ero, eto oro aje, eto ti oselu, biba ara eni se po,awon ti o ni se pelu awon arojinle wa, awon ti o ni se pelu iwoye wa nipa agbaye.

Wo Idagbasoke Awujo.

العربيّة:تطوير,  বাংলা : উন্নয়ন,  Deutsch: Entwicklung,  English: development,  Español: desarrollo,  Euskera: garapena,  Ewe: idagbasoke,  Filipino/Tagalog: kalinangan,  Français: développement,  Galego: desenvolvemento,  Italiano: sviluppo,  日本語: 発展,  Malay: pembangunan,  Português: desenvolvimento,  Română: dezvoltare,  Somali: horumarka,  Tiên Việt: sự phát triển

 

AWON EKA ASA

Awon Eka Asa

Okookan ninu awon eka wonyi ni o ni awon ohun ti o nii se pelu ona iba ara eni se ati asa ( fun apere ona oro aje) ti o ko ara won jo papo di idipo ona ise ninu.

Awon eka mefa naa ni: imo ero, oro aje, iselu, iba ara eni se papo, arojinle ati imoye.

Ni iwon bi a se le ri aworan awujo ninu asa won ati eto iba ara eni gbe po, awon eka mefefa wonyi na nii se pelu awujo.  Wo: Awon Eka.

العربيّة:أبعاد الثقاف ة,  বাংলা : সংস্কৃতির মাত্রা,  Deutsch: kulturdimensionen,   English: dimensions of culture,  Español: dimensiones de la cultura,  Euskera: kulturaren dimentsioak,  Ewe: awon eka asa,  Filipino/Tagalog: dimensyon ng kultura,  Français: dimensions de culture,  Galego: dimensións da cultura,  Italiano: dimensioni della cultura,  日本語: 文化の側面,  Malay: dimensi budaya,  Malay: dimensi budaya,  Română: dimensiunile culturii,  Somali: geybaha,  Tiên Việt: những yếu tố văn hoá

 

ARUN

Arun je okan ninu awon ona marun pataki fun ifi- ara-han osi.

Ina-wo a din ku, yio si fi oju anu han, beeni yio si wulo sii fun awujo kan lati da owo arun duro ju ati lati woo san lo. Ati lati da oju iwonba alumoni ti won ba ni ko sise iwosan awon arun ti o wo po ti o n da oju ko opolopo awon eniyan ni ilu ju ki a se inawo rira awon irin ise ati sise awari awon ogbon amu-se ti a fi le wo awon oloro die (eyi ni idi ti ajo ti o n se agbateru fun eto iwosan ni gbogbo agbaye (WHO) fi se atilehin fun agbekale eto iwoasan-alabode (PHC)).

Niwon igba ti o ti mo eyi, iwo gege bi olusekoriya le pe awujo kan ni ija igbese won lati koko lati ni ile-iwosan lia ronu jinle, ati lati le mun won se akiyesi iwa ologbon ti o wa ninu ki won o koko yan lati ni eto fun omi ati imo-toto ki a le ba se idena fun awon arun ti a le ko lati inu omi.

العربيّة:مرض,  বাংলা : রোগ,  Deutsch: Krankheit,  English: disease,  Español: enfermedad,  Euskera: gaixotasuna,  Ewe: arun,  Filipino/Tagalog: sakit,  Français: maladie,  Galego: enfermidade,  Italiano: malattia,  日本語: 病気,  Malay: penyakit,  Português: doença,  Română: boala,  Somali: cudur,  Tiên Việt: dịch bệnh

 

IWA AIJE OLOOTO

Aini iwa omoluabi ati iwa iaje olooto.

Aije olooto je okan ninu awon ona marun pataki fun ifi- ara-han osi.

Opolopo akole ni o maa n ni, bii, iwa ibaje, iko-owo-na, ilo-ni-lowo-gba, ati ole. Eyi maa n sele nigbati a ba da ori oro ti o ye ki a lo fun ilosiwaju ilu ko ibi miran fun igbadun awon eniyan kereje kan ti won ti se lodi si igbekele ti awon eniyan ni ninu won, ni ona aito ati ni koko.

Abayori aini igbagbo ninu eni yi ni osi ati ki awon eniyan ma ni itara fun oro ilu.  Idi ni eyi ti iwo gege bi olusekoriya ati eniti o n se agbateru fun awon akojopo awon eniyan, gbodo si igbelarege fu iwa ako-ya-wo, iwa omoluabi, ati jije olooto ni gbogbo awon apejopo ti a ba n se amojuto won.

العربيّة:فساد,  বাংলা : অসততা,  Deutsch: korruption, unehrlichkeit,  English: corruption, dishonesty,  Español: falta de honradez,  Euskera: zintzotasun eza,  Ewe: iwa aije olooto,  Filipino/Tagalog: di-matapat,   Français: malhonnêteté,  Galego: deshonestidade,  Italiano: disonestà,  日本語: 不正直,  Kiswahili: rushwa,  Malay: ketidakjujuran,  Português: desonestidade,  Română: necinste,  Somali: daacaddarro,  Tiên Việt: tính không thành thật,

 

SISE (kiko eko nipa sise)

Ninu gbogbo awon ona ti a fi n ko eko (iwe kika, fifi eti sile gbo oro, wiwo (tabi sise akiyesi)) eyi ti o mu-na-doko ju ni nipa "sise." Wo Awon Ogbon ida-ni-leko.

Ara awon ogbon ida-ni-leko nipa sise ni ki a kopa san an ninu sise ohun kan labe amojuto enikan ti o n se ikoni, tabi ni ona miran nipa nini owo si tabi nipa kikopa ninu ere sise.

العربيّة:عمل (التعلّم عن طريق العمل),  বাংলা : কাজ করে শেখা,  Bahasa Indonesia: bekerja,  Deutsch: handeln,  Ελληνικά: Πράξη,  English: doing,  Español: practicar,  Euskera: egitea (eginez ikastea),  Ewe: sise,  Filipino/Tagalog: paggawa,  Français: faire,  Galego: facer,  हिन्दी (Hindi): लोकतन्त्र,  Italiano: learning by doing,  日本語: 実技,  Malay: membuat, melakukan,  Nederlands: doen,  Português: agir, faça, fazendo,  Română: a practica,  Tiên Việt: làm  اردو (Urdu): عمل,

 

ISEDA

A ma a n lo oro ti a pe ni iseda lati se iyato laarin aru eda ti aniyan je, boya 'ako' tabi 'abo'

o yato die si oro ti a pe ni " iru eniyan" wti amaa n lo lati se iyato laarin "okunrin" ati "obinrin."

Oro ti pe iseda, ati awon adape ohun ti a pe ni ako ati abo yato gidigidi si ara won laarinasa kan si omiran ati lati awujo kan si omiran.

Ohun ti o kan wa ni ori oro iseda ni lati se ate-ju-mo bi iyato laarin won se le ni ipa lori pipin agbara, iba-ara-eni-se- po ninu oro aje, ati iyato to o wa laarin awon olori-io-ri awon eniyan ni ilu.

Awon ohun wonyi je awon ohun ti o se pataki ti o maa n ko ipa lori awon awujo, a si maa ni ipa lori iru ise ti olusekoriya kookan nse. 

Gegebi i amuye fun kiko eko nipa awujo kan, olusekoriya gbodo ni oye nipa awon ohun ti a kara-ma-siki re, ihuwasi, ati awon ohun ti oye re ye awon olugbe awujo. 

Olusekiriya tun gbodo sise lati ri pe a je ki awon iwa oselu ti ko to, ati iyato laarin bi oro aje olorijori ti ri ki o din ku, gegebii ano pataki lati kan lati fun awujo ni agbara sii..  Wo iwe idanileko lori Iseda.  Tun wo:  Ojo-ori, Eya ati Okunrin oun obiririn.

العربيّة:جندر (تصنيف غير بيولوجي للجنس,  বাংলা : লিঙ্গ,  Deutsch: gender,  English: gender,  Español: género,  Euskera: generoa,  Ewe: iseda,  Filipino/Tagalog: pangkasarian o kasarian,  Français: genre,  Galego: xénero,  Italiano: genere,  日本語: ジェンダー,  Kiswahili: ujinsia,  Malay: gender,  Português: género,  Română: gen,  Somali: jandar,  Tiên Việt: giới tính

 

AIMOKAN

Okan ninu awon nkan marun ti o se gbogi ti o se okunfa osi ni aimokan. Opo eniyan ni a ma n ro oro ti a pe ni aimokan gege bii eebu. Ni pato, ohun ti a n so ni pe awon eniyan kan ko ni imo lori awon ohun kan; ko si ohun itiju ninu iyen.

A gbodo mo pelu, pe iwa aimokan ati iwa omugo kii se ohun kan naa, won yato gede gede si ara won. Awon agbalagba le ko eko, sugbon a ko gbodo huwa si won bi a ti le se si omode tabi ki a se won bi eni ti ko to awa. Bi a ba se bee a o se idiwo fun eko kiko won.

Aimokan tumo si pe a ko mo ohun kan, iwa omugo tumo si pe a ko ni ogbon to lati mo ohun kan, ati pe iwa ope tumo si sise tabi ai se ohun kan nigba ti a mon pe idakeji re ni o to lati se. Iwa aimokan, iwa omugo ati iwa ope yato si ara won gede gede.

العربيّة: جهل,  বাংলা : অজ্ঞতা,  Deutsch: Unwissenheit,  English: ignorance,  Español: ignorancia,  Euskera: ezjakintasuna,  Ewe: aimokan,  Filipino/Tagalog: kamangmangan,  Français: ignorance,  Galego: ignorancia,  Italiano: ignoranza,  日本語: 無知識,  Malay: ketidaktahuan,  Português: ignorância,  Română: ignoranta,  Somali: jaahilnimo,  Tiên Việt: sự thiếu hiểu biết

 

SE KORIYA

Si se koriyani lati se eto fun fifi ohun kan si ojuse ni aarin awon egbe kan tabi awujo kan.

Riru-ni-soke. Kii se ohun kan naa gan-gan pelu ki a se eto ohun kan, nitoripe ifi-si-ojuse gbodo koko sele (awon eniyan le rin bi o ti wu won) ki a to le fun ni apejee sise koriya.

A le ko sile bii "se koriya." Gege bii riruni soke ki awujo le wa laaye, ayafi pe riru-ni soke ki awujo le wa laaye yi tun ni ipa sise koriya ati sise akoso ninu.  Wo "Fifi ohun kan si ojuse."

العربيّة:يعبيء,  বাংলা : সমবেতন,  Deutsch: mobilisieren,  English: mobilize,  Español: movilización,  Euskera: mobilizatu,  Ewe: se koriya,  Filipino/Tagalog: pagbibigay-buhay, pakilusin,  Français: mobilisez,  Galego: mobilizar,  Italiano: mobilitare,  Malay: memobilisasi,  Português: mobilizar,  Română: a mobiliza,  Somali: wacyigelinta,  Tiên Việt: vận động

 

OLUSE KORIYA

Oluse koriya ni eni ti o n mun ki ori awon eniya ya lati gbe ohun kan se, lati je ki itesiwaju ki o wa. Social animator. Akowe ti o n mojuto idagbasoke awujo tabi amu-gba-legbe re.

Osise fun eto awujo. Activist. Eniti o n se agbateru ilowosi awon eniyan ni awujo. Wo: Lati Le Je Olusekoriya.

العربيّة:شخص يقوم بالتعبئة,  বাংলা : সংগঠক,  Deutsch: mobilisieren, activist,  English: mobilizer, activist, animator,  Español: activista,  Euskera: mobilizatzailea,  Ewe: oluse koriya,  Filipino/Tagalog: pakilusin,  Français: mobilisateur,  Galego: activista,  Italiano: attivista,  日本語: 訓練士または助成人,  Kiswahili: ramsisha.  Malay: pemobilisasi,  Português: ativista,  Română: mobilizator,  Tiên Việt: người vận động

 

OWO

Owo ati oro ko tumo si ohun kan naa. Owo je apere asa ti gbogbo eniyan gbodo gbagbo ti yio ba je ohun ti yio wulo.

Osee se ki a loo gegebi odiwon fun oro, ona kan lati pin orotabi se pas-paro re, ati ona lati se iko-pamo oro. (Wo " oro," ati Agbekale fun Oro).

Owo kii se oro.

لعربيّة:مال,  বাংলা : টাকা,  Deutsch: geld,  English: money,  Español: dinero,  Euskera: dirua,  Ewe: owo,  Filipino/Tagalog: pera,  Français: argent,  Galego: diñeiro,  日本語: 金銭,  Malay: wang,  Português: dinheiro,  Română: bani,  Somali: lacag,  Tiên Việt: tiền bạc

 

HIHU IWA BI OLU

Bawo ni a se n gbin olu? Se ni "a o kan fi won sinu okunkun, a o si maa fun won ni ajile ti a fi igbe maalu se."

Adape oro ni eyi ti o tumo si odi-keji kiko akoyawo.

Ni opolopo igba ni o je pe adape oro ti o buru ti a pe ni igbe ako 'bovine' ni a maa n lo dipo "igbe maalu".

العربيّة:تعتيم,  বাংলা : মাশরুম পরিচর্যা,  Deutsch: pilzaufzucht,  English: mushroom treatment,  Español: setas, cultivo de setas,  Euskera: onddoaren tratamendua,  Ewe: hihu iwa bi olu,  Filipino/Tagalog: tratong kabuti,  Français: champignon, traitement de champignon,  Galego: o cultivo do champiñón,  Italiano: oscurità,  日本語: マッシュルーム扱い,  Malay: pengendalian cendawan,  Português: tratamento de cogumelo,  Română: "cultivarea" ciupercilor

 

OSI

Awon Okunfa Osi Marun

Osi kii kan se ai ni owo lowo tabi aini owo oya, o ju ai ni ore ofe si awon ohun amu-aye-derun bii omi, awon popo ona, eko, tabi ile iwosan. O je abayori “osi ti emi” ani ihuwasi ai ni ireti, ai ni mo to lori awon ohun amu-soro ti o wa ni arowoto, gbigbe ara le awon elomiran fun iranlowo, ai ni igboya ninu ara eni, idani-lagara, ai niawon ogbon ise, ai ni igbagbo si ara eni ni awujo, ai see gbokanle, ati ai ni eto iko-ra-jo-papo ni awujo; ni kukuru, ai ni eto akoso ti o mo-iyan-lori.  Wo Awon Okunfa Osi.

Osi, gegebi i arun ti o n ti inu awujo la wa, pe fun awotan ti o ti inu awujo la wa; osi kii kan se ai ni owo oya laarin awon oni-ori-je-ori awon eniyan. A le ka ese osi ni ile nipa kiko awon eniyan jo ati nipa didari awon talaka si ona ati ran ara won lowo, ati nipa nini okun sii ( ifun-lokun) nipa di da oju ko awon ipe-ni-ja ati sisegun won. Nitori naa, lati ka ese osi ni ile, o pe fun mimu ki ise-akoso fi ese mu ile sii.

العربيّة:فقر,  বাংলা : দরিদ্রতা,  Deutsch: Armut,  English: poverty,  Español: pobreza,  Euskera: txirotasuna,  Ewe: osi,  Filipino/Tagalog: Kahirapan,  Français: pauvreté,  Galego: pobreza,  Italiano: povertà,  日本語: 貧困,  Malay: kemiskinan,  Português: pobreza,  Română: saracie,  Somali: faqri,  Tiên Việt: sự nghèo đói

 

DIDA OWO OSI DURO

Oro ti a pe ni "dia owo owo duro" tumo si ki a mu irora kuro fun igba die.   Ki fun awon talaka ni owo ko da osi duro.

Gegebii olusekoriya ti o fi ara re jin fun ati da oju ija ko orisun osi, dipo awon afihan re, a gbodo yago fun yiyan ipa pe a kan n fun awon eniyan ni owo.

لعربيّة:تسكين الفقر,  বাংলা : দারিদ্র উপশম,  Deutsch: Armutslinderung,   English: poverty alleviation,  Español: alivio de la pobreza,  Euskera: txirotasuna arintzea,  Ewe: dida owo osi duro,  Filipino/Tagalog: pagpapawi sa kahirapan,  Français: allégement de pauvreté,  Galego: alivio da pobreza,  Italiano: alleviare la povertà,  日本語: 貧困の軽減,  Malay: peringanan kemiskinan,  Português: alívio de pobreza,  Română: alinarea saraciei,  Somali: yareynta faqriga,  Tiên Việt: xoá đói giảm nghèo

 

SISE IMUKURO OSI

Gegebii oluse koriya, lati gbe ogun ti iru arun ti o ti inu awujo la wa bii osi pe fun pe ki a se agbe-ye-wo awon okunfa, ati gbigbe igbese lati lati mun awon okunfa yi kuro Niwon bi osi se je arun ti o ti inu awujo la wa,  ona abayo re gbodo ti inu awujo la wa.

Awon ona onibeji ti o fi ara pe ara won ti a le gba lati mun osi kuro (ti agbri-jo-po gbogbo awujo, ati nipa ti ara eni) ni a o ri ninu awon ipele onibeji nihin: Gbogbo Igbese Lati Se Koriya Fun Awujo, ati Eto Lati Pa Owo Wo'le.

العربيّة:إستئصال الفقر,  বাংলা : দারিদ্র্য দূরিকরণ,  Deutsch: Armutsbeseitigung,  English: poverty eradication,  Español: erradicación de la pobreza,  Euskera: txirotasuna ezbatzea,  Ewe: sise imukuro osi,  Filipino/Tagalog: pagpuksa sa kahirapan,  Français: extirpation de pauvreté,  Galego: erradicación da pobreza,  Italiano: alleviare la povertà,  日本語: 貧困の撲滅,  Malay: penghapusan kemiskinan,  Português: erradicação de pobreza,  Română: eradicarea saraciei,  Somali: ciribtirka faqriga,  Tiên Việt: xoá triệt để cái nghèo

 

SISE ADIN-KU FUN OSI

Oro ti a pe ni "adin-ku" tumon si lati mun ki ohun kan kere sii.  Wo Agbekale Fun Fifun Awujo Lokun.

Yato fun ohun ti a pe ni "sise adin-ku" , ni eyi ti o n se am-ou-oto fun abayori osi, sise adin-ku ni a n wo gege bii ona ti o to lati se imukuro fun osi.

العربيّة:تخفيض الفقر,  বাংলা : দারিদ্র বিমোচন,  Deutsch: Armutsreduzierung,  English: poverty reduction,  Español: reducción de la pobreza,  Euskera: txirotasuna murriztea,  Ewe: sise adin-ku fun osi,  Filipino/Tagalog: pagbabawas sa kahirapan,  Français: réduction de pauvreté,  Galego: redución da pobreza,  Italiano: riduzione della povertà,  日本語: 貧困の減少,  Malay: pengurangan kemiskinan,  Português: redução de pobreza,  Română: reducerea saracie,  Tiên Việt: giảm bớt nghèo đói

 

ETO IWOSAN ALA-BOODE

Erongba nipa eto iwosan alaboode, ti Ajo ti o n se eto ilera ni agbaye [WHO], se agbateru re ti won si se atilehin fun, je okojopo awon ofin ati ona-ise ti awon talaka ati awon eniyan ti o wa ni awon orile ede ti owo ti o n wole fun won kere ni inu didun si.

Ninu awon agbekale ti o wa ninu re ni sise atenumo lori owo nina fun eto ilera ti ko won pupo fun awon aisan ti o wopo, awon ti o n se opolopo awon eniyan ni ilu, (dipo ki a maa ko opolopo alumoni ti o won le ori eto iwosan fun awon olowo nikan.

Beeni o tun se akiyesi pe ki a se amojuto ki arun ma wo ile din inawo ku ju sise iwosan lo. a ni o maa n yori si mimun adinku ba iye awon eniyan ti o n ku, ati bi aisan se n kolu awon eniyan, eyi ti o maa n munki o ni oro aje ni ara to o si tun ni aanu omo eniyan ninu.

O tun ni iwoye pe o seese lati se idanileko funawon eniyan lati ni imo die nipa eto ilera ki won o si jade lo seaimojuto fun awon eniyan ni gbogbo awon ibi ti o wa ni koro ni orile ede, ki won o si dari awon ti aisan won ta koko si awon ako-se-mo-se eleto ilera ni awon ilu nla.

Iwoye eto iwosan alabode (PHC) je eyi ti o se pataki fun awon oluse koriya ni awon orile ede ti o je akuse, nitoripe gbogbo eniyan ni oye re gbodo ye, ati pe o je ona ti o mu-na-doko lati se pipin awon alumoni kekere ti o wa.

Awon agbekale ti eto iwosan alabode (PHC ) gbe ara le je awon eyi ti a le se amunlo re fun agbekale awon ilepa miran ni awujo, bii awon ise awujo ti o wa fun itesiwaju awon eniyan. Wo ohun ti a pe ni Eto Iwosan Alaboode (PHC).

 

RIRU-NI SOKE KI AWUJO LE WA LAAYE

Riru-ni soke Ki Awujo Le Wa Laaye tumo si pe ki a fi eemi iye sinu agbarijo waon ohun kan bii awujo.

A maa n pe ni "riru-ni soke fun iye" (sugbon ki a ma dapo pelu awon aworan cinima ti o se ere omode "cartoons"). Wo Riru-ni soke fun iye.

العربيّة:تنشيط إجتماعي,  বাংলা : সামাজিক অনুপ্রেরণা,  Deutsch: Soziale Animation,  English: social animation,  Español: animación social,  Euskera: gizarte animazioa,  Ewe: riru-ni soke ki awujo le wa laaye,  Filipino/Tagalog: pagbibigay-buhay panlipunan,  Français: animation sociale,  Italiano: animazione,  日本語: 社会活発化, 強くする,  Malay: animasi sosial,  Português: animação social,  Română: animare sociala,  Tiên Việt: lòng nhiệt tình xã hội

 

FIFUN NI LOKUN

Ifunilagbara. Nini ipa sii tabi agbara lati se aseyori ninu afojusun wa.

mu lati ni okun sii.

العربيّة:تقوية,  বাংলা : শক্তিশালীকরন,  Deutsch: Empowerment, Macht, die stärkung, Stärken,  English: capacity development, empowerment, power, strengthening,  Español: capacidad, potenciación,  Euskera: indartzea,  Ewe: fifun ni lokun,  Filipino/Tagalog: pagpapalakas,  Français: capacité, empowerment,  हिन्दी (Hindi): षमता विकास अधिकारिकरण,  Italiano: empowerment,  日本語: 強くする,  Kiswahili: kujengea uwezo,  Malay: menguatkan,  Português: capacidade, desenvolvimento de capacidade, fortalecendo,  Română: dezvoltarea capacitatii, intarire,  Pyccкий: Рaзвития,  Somali: xoojinta,  Tiên Việt: tăng cường


──»«──
This site is hosted by the Vancouver Community Network (VCN)
Nenyerber etsor susu tso nunornlor siawo mer la, dzer agbagba nana nyanya nunlorla(wo)
eye nana wo nunornlor natsia susu kpler www.cec.vcn.bc.ca

© Nutornyernyer fer nuser 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Dor tala enye Lourdes Sada
CSS conversion by Wai King Lung Matthew
──»«──
Numerdzodzro susuea: 2012.10.11


 Afermer xa

 Gormer Dzerdzer